quarta-feira, 20 de outubro de 2010

site

http://www.learnyoruba.com/index.htm


FONÓLÖJÌ YORÙBÁ


Ìró ohùn ni òpó èdè Yorùbá.
Ó ÿe pàtàkì púpõ láti máa fi àmì
sí orí àwôn fáwëêlì õrõ tí a bá kô
ní èdè Yorùbá, kí a sì tún yán àwôn
tí ó bá yç ní ìdí. Bí a kò bá ÿe bëê,
yóò ÿòro láti kà àti láti mô ìtúmõ-ôn
wôn. Àmì ohùn ni a fi þ mô ìyàtõ

láàárín àwôn õrõ tí ó jô ara wôn.

Nenhum comentário: